Jẹ́nẹ́sísì 1:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Mo sì fi gbogbo ewéko tútù ṣe oúnjẹ fún gbogbo ẹran inú igbó àti gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run àti gbogbo ohun abẹ̀mí* tó ń rìn lórí ilẹ̀.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀. Sáàmù 136:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó ń fún gbogbo ohun alààyè* ní oúnjẹ,+Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.
30 Mo sì fi gbogbo ewéko tútù ṣe oúnjẹ fún gbogbo ẹran inú igbó àti gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run àti gbogbo ohun abẹ̀mí* tó ń rìn lórí ilẹ̀.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.