Sáàmù 107:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí ó mú kí àwọn tí òùngbẹ ń gbẹ mu àmutẹ́rùn,Ó sì mú kí àwọn* tí ebi ń pa jẹ ohun rere ní àjẹtẹ́rùn.+ Sáàmù 145:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 O ṣí ọwọ́ rẹ,O sì fún gbogbo ohun alààyè ní ohun tí wọ́n ń fẹ́.+
9 Nítorí ó mú kí àwọn tí òùngbẹ ń gbẹ mu àmutẹ́rùn,Ó sì mú kí àwọn* tí ebi ń pa jẹ ohun rere ní àjẹtẹ́rùn.+