- 
	                        
            
            Jóòbù 38:41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        41 Ta ló ń pèsè oúnjẹ fún ẹyẹ ìwò,+ Tí àwọn ọmọ rẹ̀ bá ń ké jáde sí Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́, Tí wọ́n sì ń rìn kiri torí wọn ò rí nǹkan jẹ? 
 
-