Òwe 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bàbá mi kọ́ mi, ó sì sọ pé: “Kí àwọn ọ̀rọ̀ mi wà lọ́kàn rẹ digbí.+ Pa àwọn àṣẹ mi mọ́ kí o sì máa wà láàyè.+ Òwe 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí àṣẹ jẹ́ fìtílà,+Òfin jẹ́ ìmọ́lẹ̀,+Àwọn ẹ̀kọ́ inú ìbáwí sì ni ọ̀nà ìyè.+ Mátíù 6:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 “Ojú ni fìtílà ara.+ Tí ojú rẹ bá mú ọ̀nà kan,* gbogbo ara rẹ máa mọ́lẹ̀ yòò.*
4 Bàbá mi kọ́ mi, ó sì sọ pé: “Kí àwọn ọ̀rọ̀ mi wà lọ́kàn rẹ digbí.+ Pa àwọn àṣẹ mi mọ́ kí o sì máa wà láàyè.+