1 Kọ́ríńtì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí mi ò rí nǹkan tó burú nínú ohun tí mo ṣe. Àmọ́, èyí kò túmọ̀ sí pé mo jẹ́ olódodo; ẹni tó ń wádìí mi wò ni Jèhófà.*+
4 Nítorí mi ò rí nǹkan tó burú nínú ohun tí mo ṣe. Àmọ́, èyí kò túmọ̀ sí pé mo jẹ́ olódodo; ẹni tó ń wádìí mi wò ni Jèhófà.*+