- 
	                        
            
            2 Kíróníkà 20:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 Wọ́n ń gbé ilẹ̀ náà, wọ́n sì kọ́ ibi mímọ́ síbẹ̀ fún ọ, èyí tó wà fún orúkọ rẹ,+ wọ́n sọ pé, 9 ‘Tí àjálù bá dé bá wa, ì báà jẹ́ idà tàbí ìdájọ́ tí kò bára dé tàbí àjàkálẹ̀ àrùn tàbí ìyàn, jẹ́ ká dúró níwájú ilé yìí àti níwájú rẹ (nítorí orúkọ rẹ wà nínú ilé yìí),+ ká sì ké pè ọ́ pé kí o ràn wá lọ́wọ́ nínú wàhálà wa, kí o gbọ́ kí o sì gbà wá.’+ 
 
-