- 
	                        
            
            2 Sámúẹ́lì 5:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Síbẹ̀, Dáfídì gba ibi ààbò Síónì, èyí tó wá di Ìlú Dáfídì.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 134:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Kí Jèhófà, Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé, Bù kún ọ láti Síónì. 
 
-