Sáàmù 37:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ọ̀dọ̀ Jèhófà ni ìgbàlà àwọn olódodo ti wá;+Òun ni odi ààbò wọn ní àkókò wàhálà.+ Àìsáyà 43:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Èmi, àní èmi ni Jèhófà,+ kò sí olùgbàlà kankan yàtọ̀ sí mi.”+ Ìfihàn 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn èyí, mo gbọ́ ohun kan ní ọ̀run tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà!*+ Ti Ọlọ́run wa ni ìgbàlà àti ògo àti agbára,
19 Lẹ́yìn èyí, mo gbọ́ ohun kan ní ọ̀run tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà!*+ Ti Ọlọ́run wa ni ìgbàlà àti ògo àti agbára,