Sáàmù 18:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+
50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+