Sáàmù 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí àwọn ajá yí mi ká;+Wọ́n ká mi mọ́ bí ìgbà tí àwọn aṣebi bá káni mọ́,+Wọ́n wà níbi ọwọ́ àti ẹsẹ̀ mi bíi kìnnìún.+ Mátíù 27:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Ní nǹkan bíi wákàtí kẹsàn-án, Jésù ké jáde pé: “Élì, Élì, làmá sàbákìtanì?” tó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?”+ Máàkù 15:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ní wákàtí kẹsàn-án, Jésù ké jáde pé: “Élì, Élì, làmá sàbákìtanì?” tó túmọ̀ sí: “Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?”+
16 Nítorí àwọn ajá yí mi ká;+Wọ́n ká mi mọ́ bí ìgbà tí àwọn aṣebi bá káni mọ́,+Wọ́n wà níbi ọwọ́ àti ẹsẹ̀ mi bíi kìnnìún.+
46 Ní nǹkan bíi wákàtí kẹsàn-án, Jésù ké jáde pé: “Élì, Élì, làmá sàbákìtanì?” tó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?”+
34 Ní wákàtí kẹsàn-án, Jésù ké jáde pé: “Élì, Élì, làmá sàbákìtanì?” tó túmọ̀ sí: “Ọlọ́run mi, Ọlọ́run mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀?”+