Sáàmù 42:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Omijé mi ni oúnjẹ mi lọ́sàn-án àti lóru;Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+
3 Omijé mi ni oúnjẹ mi lọ́sàn-án àti lóru;Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+