-
Sáàmù 25:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi yọ̀ mí.+
-
-
Sáàmù 99:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Wọ́n ń pe Jèhófà,
Ó sì ń dá wọn lóhùn.+
-