Sáàmù 109:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti di ohun tí wọ́n fi ń ṣe yẹ̀yẹ́.+ Tí wọ́n bá rí mi, ṣe ni wọ́n ń mi orí.+