-
Sáàmù 71:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ìwọ ni mo gbára lé láti ìgbà tí wọ́n ti bí mi;
Ìwọ ló gbé mi jáde látinú ìyá mi.+
Gbogbo ìgbà ni mò ń yìn ọ́.
-
6 Ìwọ ni mo gbára lé láti ìgbà tí wọ́n ti bí mi;
Ìwọ ló gbé mi jáde látinú ìyá mi.+
Gbogbo ìgbà ni mò ń yìn ọ́.