Jòhánù 19:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Lẹ́yìn náà, nígbà tí Jésù mọ̀ pé a ti ṣe ohun gbogbo parí, kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ, ó sọ pé: “Òùngbẹ ń gbẹ mí.”+
28 Lẹ́yìn náà, nígbà tí Jésù mọ̀ pé a ti ṣe ohun gbogbo parí, kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ, ó sọ pé: “Òùngbẹ ń gbẹ mí.”+