Sáàmù 34:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó ń dáàbò bo gbogbo egungun rẹ̀;Kò sí ìkankan nínú wọn tí a ṣẹ́.+ Jòhánù 19:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ní tòótọ́, àwọn nǹkan yìí ṣẹlẹ̀ kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ pé: “Wọn ò ní ṣẹ́* ìkankan nínú egungun rẹ̀.”+
36 Ní tòótọ́, àwọn nǹkan yìí ṣẹlẹ̀ kí ìwé mímọ́ lè ṣẹ pé: “Wọn ò ní ṣẹ́* ìkankan nínú egungun rẹ̀.”+