Sáàmù 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Aláìní yìí pe Jèhófà, ó sì gbọ́. Ó gbà á nínú gbogbo wàhálà rẹ̀.+ Sáàmù 69:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nítorí Jèhófà ń fetí sí àwọn aláìní,+Kò sì ní fojú pa àwọn èèyàn rẹ̀ tó wà lóko ẹrú rẹ́.+