ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 34:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ẹ bẹ̀rù Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin ẹni mímọ́ rẹ̀,

      Nítorí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ kò ní ṣaláìní.+

  • Sáàmù 84:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nítorí Jèhófà Ọlọ́run jẹ́ oòrùn+ àti apata;+

      Ó ń ṣojú rere síni, ó sì ń fúnni ní ògo.

      Jèhófà kò ní fawọ́ ohun rere sẹ́yìn

      Lọ́dọ̀ àwọn tó ń rìn nínú ìwà títọ́.+

  • Mátíù 6:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 “Torí náà, ẹ máa wá Ìjọba náà àti òdodo Rẹ̀ lákọ̀ọ́kọ́, gbogbo nǹkan mìíràn yìí la sì máa fi kún un fún yín.+

  • Fílípì 4:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Nítorí náà, Ọlọ́run mi tí ọrọ̀ rẹ̀ kò lópin máa pèsè gbogbo ohun tí ẹ nílò pátápátá+ nípasẹ̀ Kristi Jésù.

  • Hébérù 13:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ẹ yẹra fún ìfẹ́ owó nínú ìgbésí ayé yín,+ bí ẹ ṣe ń jẹ́ kí àwọn nǹkan tó wà báyìí tẹ́ yín lọ́rùn.+ Torí ó ti sọ pé: “Mi ò ní fi ọ́ sílẹ̀ láé, mi ò sì ní pa ọ́ tì láé.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́