Sáàmù 31:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìwọ ni àpáta mi àti ibi ààbò mi;+Wàá darí mi,+ wàá sì ṣamọ̀nà mi, nítorí orúkọ rẹ.+