1 Kíróníkà 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, tìrẹ ni títóbi+ àti agbára ńlá+ àti ẹwà àti ògo àti ọlá ńlá,*+ nítorí gbogbo ohun tó wà ní ọ̀run àti ní ayé jẹ́ tìrẹ.+ Jèhófà, tìrẹ ni ìjọba.+ Ìwọ ni Ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe olórí lórí ohun gbogbo. Jóòbù 41:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ta ló kọ́kọ́ fún mi ní ohunkóhun tí màá fi san án pa dà fún un?+ Tèmi ni ohunkóhun tó wà lábẹ́ ọ̀run.+ 1 Kọ́ríńtì 10:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 nítorí pé “Jèhófà* ló ni ayé àti gbogbo ohun tó wà nínú rẹ̀.”+
11 Jèhófà, tìrẹ ni títóbi+ àti agbára ńlá+ àti ẹwà àti ògo àti ọlá ńlá,*+ nítorí gbogbo ohun tó wà ní ọ̀run àti ní ayé jẹ́ tìrẹ.+ Jèhófà, tìrẹ ni ìjọba.+ Ìwọ ni Ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe olórí lórí ohun gbogbo.
11 Ta ló kọ́kọ́ fún mi ní ohunkóhun tí màá fi san án pa dà fún un?+ Tèmi ni ohunkóhun tó wà lábẹ́ ọ̀run.+