Sáàmù 27:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ,+Darí mi ní ọ̀nà ìdúróṣinṣin nítorí àwọn ọ̀tá mi.