-
Jòhánù 15:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Mi ò pè yín ní ẹrú mọ́, torí pé ẹrú kì í mọ ohun tí ọ̀gá rẹ̀ ń ṣe. Àmọ́ mo pè yín ní ọ̀rẹ́, torí pé mo ti jẹ́ kí ẹ mọ gbogbo ohun tí mo gbọ́ látọ̀dọ̀ Baba mi.
-