Sáàmù 32:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìwọ ni ibi ìfarapamọ́ mi;Wàá dáàbò bò mí nínú wàhálà.+ Wàá fi igbe ayọ̀ ìgbàlà yí mi ká.+ (Sélà) Sáàmù 57:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+ Sefanáyà 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+
57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+
3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́. Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.* Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+