Sáàmù 72:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní àkókò rẹ̀, àwọn olódodo yóò gbilẹ̀,*+Àlàáfíà yóò sì gbilẹ̀+ títí òṣùpá kò fi ní sí mọ́.