Sáàmù 86:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí o ní sí mi pọ̀,O sì ti gba ẹ̀mí* mi lọ́wọ́ Isà Òkú.*+