Sáàmù 71:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Má ṣe gbé mi sọ nù ní ọjọ́ ogbó mi;+Má pa mí tì nígbà tí mi ò bá lágbára mọ́.+