Sáàmù 22:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ kòkòrò mùkúlú ni mí, èmi kì í ṣe èèyàn,Àwọn èèyàn ń fi mí ṣẹ̀sín,* aráyé ò sì kà mí sí.+ Sáàmù 42:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+ Sáàmù 102:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àwọn ọ̀tá mi ń pẹ̀gàn mi láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.+ Àwọn tó ń fi mí ṣẹ̀sín* ń lo orúkọ mi tí wọ́n bá fẹ́ gégùn-ún.
10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+
8 Àwọn ọ̀tá mi ń pẹ̀gàn mi láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.+ Àwọn tó ń fi mí ṣẹ̀sín* ń lo orúkọ mi tí wọ́n bá fẹ́ gégùn-ún.