Sáàmù 126:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rín kún ẹnu wa,Ahọ́n wa sì ń kígbe ayọ̀.+ Ní àkókò yẹn, wọ́n ń sọ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè pé: “Jèhófà ti ṣe àwọn ohun ńlá fún wọn.”+ Àìsáyà 26:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà, o máa fún wa ní àlàáfíà,+Torí pé gbogbo ohun tí a ṣe,Ìwọ lo bá wa ṣe é.
2 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rín kún ẹnu wa,Ahọ́n wa sì ń kígbe ayọ̀.+ Ní àkókò yẹn, wọ́n ń sọ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè pé: “Jèhófà ti ṣe àwọn ohun ńlá fún wọn.”+