Sáàmù 13:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà, ìgbà wo lo máa gbàgbé mi dà? Ṣé títí láé ni? Ìgbà wo lo máa gbé ojú rẹ pa mọ́ fún mi dà?+ 2 Ìgbà wo ni mi* ò ní dààmú mọ́,Tí ẹ̀dùn ọkàn mi ojoojúmọ́ á sì dópin? Ìgbà wo ni ọ̀tá mi ò ní jẹ gàba lé mi lórí mọ́?+
13 Jèhófà, ìgbà wo lo máa gbàgbé mi dà? Ṣé títí láé ni? Ìgbà wo lo máa gbé ojú rẹ pa mọ́ fún mi dà?+ 2 Ìgbà wo ni mi* ò ní dààmú mọ́,Tí ẹ̀dùn ọkàn mi ojoojúmọ́ á sì dópin? Ìgbà wo ni ọ̀tá mi ò ní jẹ gàba lé mi lórí mọ́?+