Jóòbù 36:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kì í gbé ojú rẹ̀ kúrò lára àwọn olódodo;+Ó ń fi wọ́n sórí ìtẹ́ pẹ̀lú àwọn ọba,*+ ó sì gbé wọn ga títí láé. Sáàmù 33:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wò ó! Ojú Jèhófà ń ṣọ́ àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+Àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,
7 Kì í gbé ojú rẹ̀ kúrò lára àwọn olódodo;+Ó ń fi wọ́n sórí ìtẹ́ pẹ̀lú àwọn ọba,*+ ó sì gbé wọn ga títí láé.