Sáàmù 145:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà wà nítòsí gbogbo àwọn tó ń ké pè é,+Nítòsí gbogbo àwọn tó ń ké pè é ní òtítọ́.*+ ר [Réṣì] 19 Ó ń fún àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ ní ohun tí ọkàn wọn ń fẹ́;+Ó ń gbọ́ igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́, ó sì ń gbà wọ́n.+
18 Jèhófà wà nítòsí gbogbo àwọn tó ń ké pè é,+Nítòsí gbogbo àwọn tó ń ké pè é ní òtítọ́.*+ ר [Réṣì] 19 Ó ń fún àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ ní ohun tí ọkàn wọn ń fẹ́;+Ó ń gbọ́ igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́, ó sì ń gbà wọ́n.+