Sáàmù 31:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní tèmi, jìnnìjìnnì bò mí, mo sì sọ pé: “Màá ṣègbé níwájú rẹ.”+ Àmọ́ nígbà tí mo ké pè ọ́, o gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́.+ Sáàmù 40:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Taratara ni mo fi* dúró de Jèhófà,Ó fetí sí mi,* ó sì gbọ́ igbe mi fún ìrànlọ́wọ́.+ Jónà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ó sì sọ pé: “Mo ké pe Jèhófà nígbà tí mo wà nínú ìṣòro, ó sì dá mi lóhùn.+ Láti inú* Isà Òkú* ni mo ti kígbe pé kí o ràn mí lọ́wọ́.+ O sì gbọ́ ohùn mi.
22 Ní tèmi, jìnnìjìnnì bò mí, mo sì sọ pé: “Màá ṣègbé níwájú rẹ.”+ Àmọ́ nígbà tí mo ké pè ọ́, o gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́.+
2 ó sì sọ pé: “Mo ké pe Jèhófà nígbà tí mo wà nínú ìṣòro, ó sì dá mi lóhùn.+ Láti inú* Isà Òkú* ni mo ti kígbe pé kí o ràn mí lọ́wọ́.+ O sì gbọ́ ohùn mi.