-
Sáàmù 10:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Jèhófà, kí nìdí tí o fi dúró lókèèrè?
Kí nìdí tí o fi fara pa mọ́ ní àkókò wàhálà?+
-
-
Sáàmù 71:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ọlọ́run, má jìnnà sí mi.
Ìwọ Ọlọ́run mi, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+
-