Sáàmù 41:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Aláyọ̀ ni ẹni tó bá ń ro ti àwọn aláìní;+Jèhófà yóò gbà á sílẹ̀ ní ọjọ́ àjálù. 2 Jèhófà yóò dáàbò bò ó, yóò sì pa á mọ́. A ó pè é ní aláyọ̀ ní ayé;+O kò sì ní jẹ́ kí èrò* àwọn ọ̀tá rẹ̀ ṣẹ lé e lórí.+
41 Aláyọ̀ ni ẹni tó bá ń ro ti àwọn aláìní;+Jèhófà yóò gbà á sílẹ̀ ní ọjọ́ àjálù. 2 Jèhófà yóò dáàbò bò ó, yóò sì pa á mọ́. A ó pè é ní aláyọ̀ ní ayé;+O kò sì ní jẹ́ kí èrò* àwọn ọ̀tá rẹ̀ ṣẹ lé e lórí.+