Sáàmù 145:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà ń ṣoore fún gbogbo ẹ̀dá,+Àánú rẹ̀ sì wà lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ̀. 1 Tímótì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìdí nìyí tí a fi ń ṣiṣẹ́ kára, tí a sì ń sa gbogbo ipá wa,+ torí a ní ìrètí nínú Ọlọ́run alààyè, tó jẹ́ Olùgbàlà+ onírúurú èèyàn,+ ní pàtàkì àwọn olóòótọ́.
10 Ìdí nìyí tí a fi ń ṣiṣẹ́ kára, tí a sì ń sa gbogbo ipá wa,+ torí a ní ìrètí nínú Ọlọ́run alààyè, tó jẹ́ Olùgbàlà+ onírúurú èèyàn,+ ní pàtàkì àwọn olóòótọ́.