Àìsáyà 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ẹ kọ́ bí ẹ ṣe máa ṣe rere, ẹ wá ìdájọ́ òdodo,+Ẹ tọ́ àwọn aninilára sọ́nà;Ẹ gbèjà àwọn ọmọ aláìníbaba,*Kí ẹ sì gba ẹjọ́ opó rò.”+ Hébérù 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bákan náà, ẹ má gbàgbé láti máa ṣe rere, kí ẹ sì máa pín ohun tí ẹ ní pẹ̀lú àwọn ẹlòmíì,+ torí inú Ọlọ́run máa ń dùn gan-an sí irú àwọn ẹbọ bẹ́ẹ̀.+
17 Ẹ kọ́ bí ẹ ṣe máa ṣe rere, ẹ wá ìdájọ́ òdodo,+Ẹ tọ́ àwọn aninilára sọ́nà;Ẹ gbèjà àwọn ọmọ aláìníbaba,*Kí ẹ sì gba ẹjọ́ opó rò.”+
16 Bákan náà, ẹ má gbàgbé láti máa ṣe rere, kí ẹ sì máa pín ohun tí ẹ ní pẹ̀lú àwọn ẹlòmíì,+ torí inú Ọlọ́run máa ń dùn gan-an sí irú àwọn ẹbọ bẹ́ẹ̀.+