Sáàmù 55:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ju ẹrù rẹ sọ́dọ̀ Jèhófà,+Yóò sì gbé ọ ró.+ Kò ní jẹ́ kí olódodo ṣubú* láé.+ Òwe 16:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Fi gbogbo ohun tí o bá ń ṣe lé Jèhófà lọ́wọ́,*+Ohun tí o fẹ́ ṣe á sì yọrí sí rere.