Sáàmù 62:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 62 Ní tòótọ́, mo* dúró jẹ́ẹ́ de Ọlọ́run. Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìgbàlà mi ti wá.+ Ìdárò 3:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ó dáa kí èèyàn dúró jẹ́ẹ́*+ de ìgbàlà Jèhófà.+