Òwe 11:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn tí ọkàn wọn burú jẹ́ ohun ìríra lójú Jèhófà,+Àmọ́ àwọn tí ọ̀nà wọn tọ́ ń mú inú rẹ̀ dùn.+