Sáàmù 38:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbogbo ara mi ń ṣàìsàn* nítorí ìbínú rẹ. Kò sí àlàáfíà nínú egungun mi nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mi.+