Sáàmù 18:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Jèhófà san èrè fún mi nítorí òdodo mi;+Ó san èrè fún mi nítorí pé ọwọ́ mi mọ́.*+ Sáàmù 26:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ ní tèmi, èmi yóò máa rìn nínú ìwà títọ́ mi. Gbà mí sílẹ̀,* kí o sì ṣojú rere sí mi. Sáàmù 41:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní tèmi, o ti dì mí mú nítorí ìwà títọ́ mi;+Wàá fi mí sí iwájú rẹ títí láé.+