Sáàmù 90:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ọjọ́ ayé wa* ń dín kù nítorí ìbínú ńlá rẹ;Àwọn ọdún wa ń lọ sí òpin bí ọ̀rọ̀ wúyẹ́wúyẹ́.* Jémíìsì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 bẹ́ẹ̀ sì rèé, ẹ ò mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí yín lọ́la.+ Torí ìkùukùu ni yín, tó máa ń wà fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn náà tí á pòórá.+
14 bẹ́ẹ̀ sì rèé, ẹ ò mọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí yín lọ́la.+ Torí ìkùukùu ni yín, tó máa ń wà fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn náà tí á pòórá.+