Sáàmù 90:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí bí ẹgbẹ̀rún ọdún bá kọjá, á dà bí àná lójú rẹ,+Bí ìṣọ́ kan ní òru.