2 Sámúẹ́lì 16:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣùgbọ́n ọba sọ pé: “Kí ló kàn yín nínú ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin ọmọ Seruáyà?+ Ẹ jẹ́ kó máa ṣépè fún mi,+ torí pé Jèhófà ti sọ fún un pé,+ ‘Ṣépè fún Dáfídì!’ Ta ló máa wá sọ pé, ‘Kí nìdí tí o fi ń ṣe báyìí?’”
10 Ṣùgbọ́n ọba sọ pé: “Kí ló kàn yín nínú ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin ọmọ Seruáyà?+ Ẹ jẹ́ kó máa ṣépè fún mi,+ torí pé Jèhófà ti sọ fún un pé,+ ‘Ṣépè fún Dáfídì!’ Ta ló máa wá sọ pé, ‘Kí nìdí tí o fi ń ṣe báyìí?’”