Sáàmù 90:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 O gbé àwọn àṣìṣe wa sí iwájú rẹ;*+Ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ tú àwọn àṣírí wa.+