- 
	                        
            
            Sáàmù 28:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Ó ti ràn mí lọ́wọ́, ọkàn mi sì ń yọ̀, Torí náà, màá fi orin mi yìn ín. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 140:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, Olùgbàlà mi tó lágbára, O dáàbò bo orí mi ní ọjọ́ ogun.+ 
 
-