-
Sáàmù 5:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Jèhófà, ṣamọ̀nà mi nínú òdodo rẹ nítorí àwọn ọ̀tá mi;
Mú kí ọ̀nà rẹ là fún mi.+
-
-
Sáàmù 143:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ẹ̀mí rẹ dára;
Kí ó máa darí mi ní ilẹ̀ tó tẹ́jú.*
-