-
Sáàmù 84:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Kódà ẹyẹ rí ilé síbẹ̀,
Alápàáǹdẹ̀dẹ̀ sì rí ìtẹ́ fún ara rẹ̀,
Ibẹ̀ ló ti ń tọ́jú àwọn ọmọ rẹ̀
Nítòsí pẹpẹ rẹ títóbi lọ́lá, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,
Ọba mi àti Ọlọ́run mi!
-