Sáàmù 119:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo* dùbúlẹ̀ nínú eruku.+ Mú kí n máa wà láàyè bí o ṣe sọ.+