Jémíìsì 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Tí ìfẹ́ ọkàn náà bá ti gbilẹ̀,* ó máa bí ẹ̀ṣẹ̀; tí ẹ̀ṣẹ̀ náà bá sì ti wáyé, ó máa yọrí sí ikú.+